· November, 2022

Stories about Digital Security + Language from November, 2022

Ọ̀rọ̀ Ààbò Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá…ní èdè wa. Àwọn Àbá láti ọwọ́ onígbèjà èdè Yorùbá lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

  29 November 2022

"kò fi bẹ́ẹ̀ sí àyè fún àwọn tí ó ń sọ èdè Yorùbá nítorí àìsílárọ̀wọ́tó àwọn ohun-àmúlò ẹ̀kọ́ ẹ̀rọ-ayárabíàṣá wọ̀nyí ní èdè Ìbílẹ̀ wọn, èyí tí ó ti dá kún àìní àṣà ààbò ẹ̀rọ-ayárabíàṣá ní àárín àwọn ọmọ Yorùbá náà.”